Taani alaga agbarijopo awon gomina ileyi?

Se Jonah Jang ni tabi Rotimi Amaechi? Ipade di inu ipade National Economic Council L’Abuja lati mo eniti igbakeji aare Namadi Sambo tii se alaga NEC yio fi han gege bii alaga awon gomina.

Ajo INEC gbodo fi iyawo aare Jonathan jofin -APC

Egbe oselu APC ti ni. Ajo ti o n ri si eto idibo nile wa, INEC pe won gbodo fi Patience Jonathan jofin latari bi O ti se n polongo ibi fun oko re nigbati o lo si ipinle Rivers.

Ajo INEC gbodo fi iya aare Jonathan jofin -APC

Egbe oselu APC ti ni. Ajo ti o n ri si eto idibo nile wa, INEC pe won gbodo fi Patience Jonathan jofin latari bi O ti se n polongo ibi fun oko re nigbati o lo si ipinle Rivers.

Eru Spain ko ba wa – Stephen Keshi, Vincent Enyeama

Akoni egbe agbaboolu Super Eagle, Stephen Keshi ati amule Vincent Enyeama ti fidi re mule pe eru awon Spain ko ba awon. Ni ojo Aiku ti o n bo ni won yio maa koju ara won ninu idije FIFA Confederation ti O n lo lowo ni Brazil.

Awon agbaagba oke -Oya ti ni awon ko fi owo si Jonathan fun odun 2015

Lori ipo idibo aare ile yi ti yio waye ni odun 2015, Awon agbaagba apa oke -Oya ti ni awon ko fi owo si Jonathan

Egbe agba boolu Super Eagle

Nje oseese, leyin igba ti orileede Uruguay ti na Super eagle pelu amin ayo meji si eyokan, lati pegede lo si ipele ti Oº°˚˚˚°º kan? Se won a le na Awon akegbe won lati orileede Spain? Kini ero yin

Nibo ni ori n ba ese re?

Oro ado oloro ti o n fi ojoojumo n bu ni orileede yi, nigbawo ni awon Ijoba yio wa nkan se sii?

Facebook ti se tan bayi lati ra Whatsapp

Ile ise ti oni Facebook ti se tan bayi lati ra Whatsapp pelu owo ti o to bilionu merindinlogun owo dollar ($16bn).

Aare Jonathan ti yo Sanusi Lamido

Aare Jonathan ti yo Gomina Bank apapo ile yi (CBN), malam Lamido Sanusi o si ti yan Sarah Alade gege bi adele

Kiise ohun ti o dara bi Jonathan ko se lo ki Olubadan – Awon oloye ilu Ibadan

Ni ipari ose yi ni aare Jonathan wa si ipinle Oyo ti o si lo ki awon Oba kan ti won wa ni ile Yoruba, lara won ni Ooni Ile-Ife ati Alaafin Oyo. Sugbon o ko lati ya odo Olubadan bi o ti le je pe ilu papako ofurufu ti Ibadan ni baalu re ti bale, Eyi lomu ki awon agbaagba oloye Ile Ibadan fi wipe Jonathan ko se daada

Obasanjo si Amaechi

OBASANJO ON AMAECHI: “I believe I took a decision I believed was right. When I took it, I had no apology. I fast and pray to take decisions on i  mportant issues. When I have something that requires action, it must be taken, otherwise I am not a worthy leader. A report came on Amaechi which indicated that there were some issues and I said yes, there are some issues, going by the report. I found the judgment awkward in the sense that, how can a man who had not contested an election, was not voted for, be declared winner? I laugh about it, but kept quiet. He took it to the higher court and at the Supreme Court, he won and that was the end. As far as I am concerned, the issues have been straightened out… I phone Amaechi not to take anything against his predecessor. Hold me responsible for whatever decision taken against you, not your predecessor. When you invited me, many people said I should not come. They said for security. There is nothing more dangerous than fear. At my age what should I fear even if it is death? If I die tomorrow, send a cow for my funeral. They told me that one road named after me was cancelled by you (Amaechi). Why should I come, they asked me? If anybody named anything after me, good luck to him. I am not working for Nigerians to name roads after me. I want my name to be in the minds and heart of people of the world, not necessarily on roads. If you invite me and I didn’t come because of the road that was cancelled, then I don’t deserve to be honoured, I will be petty.” – Olusegun Obasanjo.

Aku isimi

Aku isimi opin ose